Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìròyìn Kárí Ayé

 

2020-04-08

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #2

Ẹ máa rí bí Jèhófà ṣe ń tọ́ ètò rẹ̀ sọ́nà lásìkò tí nǹkan ò dẹrùn yìí àti bí wọn ṣe ń lo àwọn alàgbà onífẹ̀ẹ́ láti bójú tó wa.

2020-04-06

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #1

Gbọ́ nípa bí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní South Korea, Ítálì àti orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ṣe ń bá àrùn tó ń jà ràn-ìn báyìí yí.

2020-04-06

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàjáwìrì Kárí Ayé: Bá A Ṣe Ń Ran Àwọn Ará Wa Lọ́wọ́ Tí Àjálù Àtàwọn Pàjáwìrì Míì Bá Ṣẹlẹ̀

Ìgbìmọ̀ Olùdarí á máa fún àwọn ará kárí ayé ní ìtọ́ni tó bọ́ sásìkò nígbà tí àjálù bá ṣẹlẹ̀.

2020-03-05

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Àrùn Corona àti Àwọn Ohun Tó Yẹ Ká Ṣe

Ka àwọn ohun tó máa jẹ́ kó o lè dènà àrùn náà tó bá ṣẹ̀lẹ̀ pé ó ṣọṣẹ́ ní àdùúgbò rẹ.