Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìròyìn Kárí Ayé

 

2020-11-20

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #8

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí jẹ́ ká mọ bí àwọn àsọtẹ́lẹ̀ inú Bíbélì ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti ní ìfaradà lásìkò tí àjàkálẹ̀ àrùn ń jà ràn-ìn yìí.

2020-10-23

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #7

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ sọ ohun táwọn ọ̀dọ́ lè ṣe láti kojú àwọn ìṣòro tí àjàkálẹ̀ àrùn yìí ń fà.

2020-09-04

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #6

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí jẹ́ ká rí i pé àjàkálẹ̀ àrùn yìí ò dá oúnjẹ tẹ̀mí dúró rárá.

2020-09-03

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #5

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí jẹ́ ká rí àwọn ọ̀nà tí Jèhófà ń gbà fi ìfẹ́ tọ́jú wa lásìkò tí àrùn gbẹ̀mígbẹ̀mí ń tàn kálẹ̀ yìí.

2020-06-24

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #4

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí jẹ́ ká rí àwọn ìlànà Ìwé Mímọ́ tó máa ràn wá lọ́wọ́ láti ṣèpinnu tó tọ́ tá a bá fẹ́ bẹ̀rẹ̀ àwọn nǹkan tá a máa ń ṣe nínú ìjọsìn Jèhófà pa dà.

2020-05-20

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #3

Ẹ máa rí bí Jèhófà ṣe bù kún ètò tá a ṣe fún àkànṣe àsọyé àti Ìrántí Ikú Kristi tá a ṣe lọ́dún yìí.