Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìròyìn Kárí Ayé

 

2021-11-23

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #9

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fún àwọn ará níṣìírí, ó sì tún jẹ́ ká gbọ́rọ̀ lẹ́nu àwọn ará tó ti bẹ̀rẹ̀ sí í ṣèpàdé ní Gbọ̀ngàn Ìjọba.

2021-10-04

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #8

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ àwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ lẹ́nu àìpẹ́ yìí, ó sì tún sọ ẹsẹ Ìwé Mímọ́ ti ọdún 2022.

2021-08-31

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #7

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí gbà wá níyànjú pé ká máa wà níṣọ̀kan.

2021-08-12

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #6

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fún àwọn àgbàlagbà níṣìírí, ó sì sọ fún wa bí nǹkan ṣe ń lọ sí lẹ́nu iṣẹ́ ìkọ́lé.

2021-07-27

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #5

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fún àwọn ìdílé ní ìṣírí, ó sì sọ ìrírí tó máa jẹ́ káwọn ìdílé lè fara da àsìkò àjàkálẹ̀ àrùn yìí.

2021-05-31

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #4

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ ìròyìn nípa bí nǹkan ṣe ń lọ sí, títí kan àwọn ìrírí tó jẹ́ ká mọ bí Jèhófà ṣe ń ràn wá lọ́wọ́ láti “ja àjàṣẹ́gun” láìka àwọn ìṣòro tá à ń kojú sí.

2021-04-18

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #3

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ àwọn ìrírí àti ìròyìn tó jẹ́ ká rí bí Jèhófà ṣe ń bù kún iṣẹ́ ìwàásù tá à ń ṣe lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn yìí.

2021-03-15

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #2

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ àwọn ìròyìn àti ìrírí tó ń gbéni ró, wọ́n jẹ́ ká rí bí Jèhófà ṣe ń bù kún iṣẹ́ Bẹ́tẹ́lì àtàwọn tó ń sìn níbẹ̀ lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn yìí.

2021-02-10

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #1

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ àwọn ìrírí tó ń gbéni ró fún wa, àwọn ìrírí yìí jẹ́ ká rí bí Jèhófà ṣe ń bù kún iṣẹ́ ìwàásù wa lásìkò tí àjàkálẹ̀ àrùn yìí ń ṣọṣẹ́.

2020-12-25

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #9

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí ṣàlàyé ìdí tí kò fi yẹ ká dẹwọ́ láti máa dáàbò bo ara wa ká má bàa kó àrùn Corona yìí.