Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

JANUARY 28, 2022
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2022 #1

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2022 #1

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ bí nǹkan ṣe ń lọ nínú ètò Ọlọ́run lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn yìí, ó sì gbà wá níyànjú pé ká wà lójúfò kí ohunkóhun má bàa ba àjọṣe wa pẹ̀lú Jèhófà jẹ́.