Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

NOVEMBER 20, 2020
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #8

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #8

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí ṣàlàyé bí àwọn àsọtẹ́lẹ̀ tó ń ṣẹ lónìí ṣe ń jẹ́ ká túbọ̀ nígbàgbọ́ pé Ìjọba Ọlọ́run ò ní pẹ́ dé. Wọ́n sì tún sọ àwọn ìrírí tó ń gbéni ró fún wa.