Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

OCTOBER 16, 2020
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #7

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #7

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fi Ìwé Mímọ́ gbà wá níyànjú, a tún gbọ́rọ̀ látẹnu àwọn ọ̀dọ́ kan láti ibi gbogbo láyé.