Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

SEPTEMBER 4, 2020
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #6

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #6

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fi Ìwé Mímọ́ gbà wá níyànjú, àwọn arákùnrin àti arábìnrin láti orílẹ̀-èdè Ethiopia, Mòsáńbí ìkì àti Central Amẹ́ríkà sọ àwọn ìrírí tó ń gbéni ró fún wa.