Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

JULY 24, 2020
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #5

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #5

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fi Ìwé Mímọ́ gbà wá níyànjú, àwọn arákùnrin àti arábìnrin láti orílẹ̀-èdè Àǹgólà, Mòsáńbí ìkì àti Rọ́ṣíà sọ àwọn ìrírí tó ń gbéni ró fún wa.