MAY 15, 2020
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ
Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #3
Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fi Ìwé Mímọ́ gbà wá níyànjú, àwọn arákùnrin láti orílẹ̀-èdè Haiti àti Congo (Kinshasa) náà sọ àwọn ìrírí tó ń gbéni ró fún wa.

