MARCH 18, 2020
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ
Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #1
Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fún wa níṣìírí látinú Ìwé Mímọ́, wọ́n tún fọ̀rọ̀ wá àwọn arákùnrin láti Ítálì, Korea, àti orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lẹ́nu wò.

