Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

APRIL 8, 2020
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #2

Ìròyìn Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #2

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fi Ìwé Mímọ́ gbà wá níyànjú, àwọn arákùnrin láti orílẹ̀-èdè Canada àti Philippines náà sọ àwọn ìrírí tó ń gbéni ró fún wa.