Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

JANUARY 16, 2014
ÀMÉNÍÀ

Ìjọba Àméníà Dá Àwọn tí Ẹ̀rí Ọkàn Ò Jẹ́ Kí Wọ́n Ṣiṣẹ́ Ológun Sílẹ̀

Ìjọba Àméníà Dá Àwọn tí Ẹ̀rí Ọkàn Ò Jẹ́ Kí Wọ́n Ṣiṣẹ́ Ológun Sílẹ̀

Ní November 12, 2013, ìjọba Àméníà dá gbogbo àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà yòókù tí wọ́n fi sẹ́wọ̀n torí pé ẹ̀rí ọkàn ò jẹ́ kí wọ́n ṣiṣẹ́ ológun sílẹ̀. Fídíò yìí jẹ́ ká rí bí ìpinnu mánigbàgbé kan tí ilé ẹjọ́ ṣe ṣe mú kí ìjọba dá àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà yìí sílẹ̀.