Àméníà
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Orílẹ̀-èdè Àméníà
-
Iye àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà—11,575
-
Iye àwọn ìjọ—128
-
Iye àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi—25,606
-
Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún—267
-
Iye èèyàn—3,040,000
Bó Ṣe Di Pé Ìjọba Àméníà Fọwọ́ sí I Pé Èèyàn Lẹ́tọ̀ọ́ Láti Sọ Pé Ẹ̀rí Ọkàn Ò Jẹ́ Kóun Ṣiṣẹ́ Ológun
Ìtàn ohun tó ti ṣẹlẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ àwọn tí ẹ̀rí ọkàn ò jẹ́ kí wọ́n ṣiṣẹ́ ológun ní Àméníà jẹ́ ká rí i bí àwọn ẹjọ́ tí ECHR dá ṣe nípa pàtàkì lórí ọwọ́ tí ìjọba fi ń mú àwọn tí ẹ̀rí ọkàn ò jẹ́ kí wọ́n ṣiṣẹ́ ológun.
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Tó Kọ́kọ́ Ṣe Iṣẹ́ Àṣesìnlú Lórílẹ̀-èdè Àméníà Ti Parí Ẹ̀
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Àméníà ń ṣe ojúṣe wọn fún ìjọba lọ́nà tó máa ṣe orílẹ̀-èdè wọn àtàwọn aráàlú láǹfààní, láì ṣohun tí ò bá ẹ̀rí ọkàn wọn mu.
Ìjọba Àméníà Dá Àwọn tí Ẹ̀rí Ọkàn Ò Jẹ́ Kí Wọ́n Ṣiṣẹ́ Ológun Sílẹ̀
Báwo ni ìpinnu mánigbàgbé kan tí ilé ẹjọ́ ṣe ṣe mú kí ìjọba dá àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà yìí sílẹ̀?