Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

MARCH 22, 2019
RỌ́ṢÍÀ

ÀKÀNṢE ÌRÒYÌN: Ìjọba Ń Bá A Lọ Láti Máa Ṣenúnibíni Sáwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà

ÀKÀNṢE ÌRÒYÌN: Ìjọba Ń Bá A Lọ Láti Máa Ṣenúnibíni Sáwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Ìròyìn yìí dá lórí ohun tó ṣẹlẹ̀ sáwọn ará wa lórílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà lẹ́nu àìpẹ́ yìí. Ìròyìn náà sọ̀rọ̀ nípa bí wọ́n ṣe gbọ́ ẹjọ́ àwọn kan, bí wọ́n ṣe fi àwọn kan sẹ́wọ̀n, bí wọ́n ṣe gbẹ́sẹ̀ lé àwọn ilé ètò Ọlọ́run, àti báwọn ọlọ́pàá ṣe ya wọ ilé àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà.

Wà á jáde lédè Gẹ̀ẹ́sì