Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

JUNE 22, 2020
RỌ́ṢÍÀ

Kò Yẹ Ká Bẹ̀rù Inúnibíni

Kò Yẹ Ká Bẹ̀rù Inúnibíni

Nígbà ìpàdé ọdọọdún ti ọdún 2019, Arákùnrin Mark Sanderson tó jẹ́ ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ àsọyé tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ “Kí Ló Yẹ Ká Bẹ̀rù?” Fídíò yìí wà nínú àsọyé yẹn, ibẹ̀ ni wọ́n ti sọ ìrírí àwọn ará wa kan tí wọ́n ṣe inúnibíni sí lórílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà.