Yorùbá
Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #4
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/702020283/univ/art/702020283_univ_sqr_xl.jpg

JUNE 19, 2020
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #4

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2020 #4

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fi Ìwé Mímọ́ gbà wá níyànjú, àwọn arákùnrin láti orílẹ̀-èdè Brazil àti Ecuador náà sọ àwọn ìrírí tó ń gbéni ró fún wa.