Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Bó O Ṣe Lè Lo JW.ORG

Bó O Ṣe Lè Lo JW.ORG

Kọ́ bó o ṣe lè lo ìkànnì jw.org kó lè wúlò fún ẹ dáadáa.

Bó O Ṣe Lè Wá Ìtẹ̀jáde

Lo àwọn àbá tó rọrùn yìí kó o lè rí ìtẹ̀jáde tó ò ń wá. Kọ́ bó o ṣe lè wá àkòrí ìtẹ̀jáde, ìwé ìròyìn pàtó kan, oríṣi ẹ̀dà tó wà tàbí ohun pàtó tó wà nínú ẹ̀ lórí ìkànnì jw.org.

Bó O Ṣe Lè Wá Nǹkan ní Èdè Míì

Kọ́ bó o ṣe lè yí èdè tó o fi ṣí ìkànnì pa dà, bó o ṣe lè ṣí abala kan ní èdè míì tàbí kó o wá ìtẹ̀jáde ní èdè míì.

Wo Fídíò Lórí JW.ORG

Wá fídíò, kó o sì wò ó, wo gbogbo fídíò tó wà ní ìsọ̀rí kan, ṣe fídíò bó o ṣe fẹ́, yan irú fídíò tó o fẹ́.

Bó O Ṣe Lè Lo Ìkànnì JW.ORG Lórí Fóònù

Kọ́ bó o ṣe lè lọ sí àwọn ìsọ̀rí tó wà, àwọn ìtẹ̀jáde àti Bíbélì orí íńtánẹ́ẹ̀tì, tàbí kó o gbọ́ àtẹ́tísí àpilẹ̀kọ kan.

Bó O Ṣe Lè Lo Ẹ̀dà Bíbélì Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

Àwọn ìdálẹ́kọ̀ọ́ àtàwọn àbá nípa bó o ṣe lè lo àwọn ohun tá a fi ń kẹ́kọ̀ọ́ àtàwọn ohun tó wà nínú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun (ẹ̀dà tó wà fún ìkẹ́kọ̀ọ́).

Fi Ìlujá Àpilẹ̀kọ, Fídíò Tàbí Ìtẹ̀jáde Kan Ránṣẹ́

Bó o ṣe lè fi ìlujá àpilẹ̀kọ, fídíò tàbí ìtẹ̀jáde tó wà lórí ìkànnì jw.org ránṣẹ́.

Bó O Ṣe Lè Lo Ìwé “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà

Kọ́ bó o ṣe lè lo gbogbo ẹ̀da ìwé orin wa tó jẹ́ ti orí ẹ̀rọ.

Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè​—JW.ORG

Wo ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè tí àwọn èèyàn sábà máa ń béèrè.