Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí TV.JW.ORG Ń Lò
Oríṣiríṣi ìsọfúnni kéékèèké ló wà, iṣẹ́ wọn sì yàtọ̀ síra, àmọ́ gbogbo wọn ló máa jẹ́ kó o lè gbádùn ìkànnì yìí. Àpẹẹrẹ bá a ṣe ń lo àwọn ìsọfúnni kéékèèké àtàwọn ohun míì tó jọ ọ́ ló wà nísàlẹ̀ yìí.
Orúkọ |
Ìdí |
Ìgbà a |
Oríṣi |
|---|---|---|---|
INSIGHT_CLIENT_ID, SESSION_COUNT, insight-${featureID}-usageInfo |
A máa ń fi gba ìsọfúnni nípa bí ẹnì kan ṣe ń lo ìkànnì kan. A máa wá fi ìsọfúnni yìí ṣàkójọ báwọn èèyàn ṣe ń lo ìkànnì náà sí, àá sì fi mú kí ìkànnì náà sunwọ̀n sí i. A kì í béèrè kúlẹ̀kúlẹ̀ nípa ẹni tó ń lo ìkànnì náà, ìsọfúnni tá a máa ń gbà ò ju irú browser tó ń lò, irú fóònù tàbí kọ̀ǹpútà tó ń lò, ibi tó ti ń lo ìkànnì náà, iye ìgbà tó ti lo ìkànnì náà tàbí apá kan níbẹ̀ àti bó ṣe máa ń pẹ́ tó láwọn apá ibì kan lórí ìkànnì náà. |
Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage) |
Ìsọfúnni Tá A Fi Ń Ṣèwádìí |
LANGUAGE |
Ó máa ń jẹ́ kí ẹnì kan lè wọ ìkànnì náà tààràtà ní èdè kan náà tó ti yàn tẹ́lẹ̀ lórí https://tv.jw.org/ |
Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage) |
Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì |
FAVORITE_CHANNEL |
Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè wo ètò tẹlifíṣọ̀n tó yàn láàyò tó bá ti yan apá tá a pè ní “Ètò Tó Ń Lọ Lọ́wọ́”. |
Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage) |
Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì |
LAST_STREAMING_CHANNEL |
Ó jẹ mọ́ ìsọfúnni ti FAVORITE_CHANNEL. Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè pa dà sí ètò tẹlifíṣọ̀n tó wò gbẹ̀yìn tó bá jẹ́ pé ohun tó sàmì sí níbi ètò tẹlifíṣọ̀n tó yàn láàyò ni ‘èyí tí mo wò gbẹ̀yìn’. |
Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage) |
Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì |
MEDIA:${mediaID} |
Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè pa dà bẹ̀rẹ̀ àtẹ́tísí kan tàbí fídíò kan tó ń wò níbi tó gbọ́ ọ tàbí wò ó dé. |
Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage) |
Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì |
PREFERRED_RESOLUTION |
Á jẹ́ kí ẹnì kan lè máa wo fídíò bó bá ṣe fẹ́ kó lágbára tó, tó bá ti lè yàn án lẹ́ẹ̀kan. |
Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage) |
Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì |
SUBTITLES |
Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè máa rí àkọ́lé àwọn fídíò, tó bá ti lè yàn án lẹ́ẹ̀kan. |
Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage) |
Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì |
Tún wo Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí Àwọn Ìkànnì Wa Ń Lò.
a Tá a bá sọ pé ìsọfúnni kan jẹ́ èyí tí “Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)”, ohun tá à ń sọ ni pé orí ìkànnì wa kọ́ ni ìsọfúnni náà máa pa mọ́ sí, orí browser tí ẹni náà fi ń lọ sórí ìkànnì ni. Torí náà, irú àwọn ìsọfúnni yìí kì í lọ́jọ́ tó máa pa rẹ́, torí ó máa wà lórí browser yẹn títí, àfi tí ẹni náà bá pa àwọn ìsọfúnni tó wà lórí browser ẹ̀ rẹ́.

