Yorùbá
Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí WWW.JW.ORG Ń Lò
/assets/ct/79e1b14fff/images/syn_placeholder_sqr.png

Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí WWW.JW.ORG Ń Lò

Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí WWW.JW.ORG Ń Lò

Oríṣiríṣi ìsọfúnni kéékèèké ló wà, iṣẹ́ wọn sì yàtọ̀ síra, àmọ́ gbogbo wọn ló máa jẹ́ kó o lè gbádùn ìkànnì yìí. Àpẹẹrẹ bá a ṣe ń lo àwọn ìsọfúnni kéékèèké àtàwọn ohun míì tó jọ ọ́ ló wà nísàlẹ̀ yìí.

Orúkọ (àwọn) Ìsọfúnni kéékèèké

Ìdí

Ìgbà a

Oríṣi

insight-${featureID}-usageInfo

A máa ń lò ó láti mọ bí ẹnì kan ṣe ń lo ìkànnì náà. A máa ń kó ìsọfúnni yìí jọ láti mú kí ìkànnì yìí sunwọ̀n sí i. Orúkọ ẹni tó ni ìsọfúnni tá a bá gbà kì í hàn nínú rẹ̀, bákan náà ni irú ètò tó fi ń ṣí ìkànnì (browser), irú ẹ̀rọ tẹ́nì náà ń lò, ibi tó ti lo ìkànnì náà, iye ìgbà tó lò ó tàbí ohun tó lò lórí rẹ̀ àti bó ṣe ń lo àwọn nǹkan tó wà lórí ìkànnì náà sí..

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tá A Fi Ń Ṣèwádìí

ckLang

Ó máa ṣí ìkànnì náà ní tààràtà fún ẹnì kan ní èdè tó lò gbẹ̀yìn lórí https://www.jw.org/.

Ọdún kan

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

otherContentLang

Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan ṣí àpilẹ̀kọ kan ní èdè tó máa ń lò jù lábẹ́ Yan Èdè Tó O Fẹ́.

Kò lọ́jọ́

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

persistentData-ACCESSIBILITY_MODE

Ó máa fàlà sí ìlujá lórí ìkànnì náà bó ṣe ń ṣí i torí pé ẹni náà sọ pé kó ṣe bẹ́ẹ̀ nígbà tó ṣí i gbẹ̀yìn.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

persistentData-AutoCompleteFeatured-contentLanguageFilter

Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè yan èdè látinú èdè tó lò gbẹ̀yìn lábẹ́ Yan Èdè Tó O Fẹ́.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

persistentData-AutoCompleteFeatured

Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè yan èdè níbi tá a ti ń yan èdè látinú èdè tó lò gbẹ̀yìn lórí ìkànnì náà.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

persistentData-AutoCompleteFeatured-${fieldID}

Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè yan ọ̀kan lára àwọn ohun tó ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn lórí ìkànnì náà láìpẹ́ sígbà yẹn.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

persistentData-${pageType}_VIEW_MODE

Tí ẹnì kan bá ṣí abala kan lórí ìkànnì náà, ó máa jẹ́ kí kọ̀ǹpútà lè to ohun tó wà níbẹ̀ tẹ̀ léra tàbí kó tò ó sẹ́gbẹ̀ẹ́ ara wọn, ó sinmi lórí èyí tónítọ̀hún bá yàn tẹ́lẹ̀.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

persistentData-${pageID}${accordionID}

Ó máa jẹ́ kí àwọn ohun tó ń sún abala kì sí tàbí pa dé lórí abala tí ẹnì kan ṣí, ó sinmi lórí ohun tónítọ̀hún bá yàn tẹ́lẹ̀.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

persistentData-slContentToggleControlState

Ó máa jẹ́ kí ẹni tó ń wo abala kan lórí ìkànnì ní èdè àwọn adití lè rí àwọn ọ̀rọ̀ tó wà ní abala náà kà tàbí kó gbé e kúrò, bó bá ṣe fẹ́ ẹ sí.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

persistentData-mid${pageID}-${languageCode}-ReadStatus

Ó máa jẹ́ ká lè ta ẹnì kan lólobó nípa àwọn ìfilọ̀ tuntun tí kò tíì kà.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

persistentData-mid${pageID} -verified-${year}

Tí ẹnì kan bá lọ sí abala kan lórí ìkànnì tí kọ̀ǹpútà ti máa ń béèrè àwọn nǹkan kan kó tó wọlé síbẹ̀, ó máa jẹ́ kó ṣeé ṣe pé ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣo lọ́dún ni ẹni náà máa tẹ bọ́tínì tó fi hàn pé òun gba ohun tí ìkànnì náà sọ wọlé.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

${featureID}Enabled

Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè máa ṣe ohun tó ń ṣe lórí ìkànnì náà nígbà tó wọbẹ̀ gbẹ̀yìn.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

lesson-${pageID}-${languageCode}-progress

Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè pa dà sí àwòrán tó wò gbẹ̀yìn nígbà tó ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lórí íńtánẹ́ẹ̀tì.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

Tún wo Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí Àwọn Ìkànnì Wa Ń Lò.

a Tá a bá sọ pé ìsọfúnni kan jẹ́ èyí tí “Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)”, ohun tá à ń sọ ni pé orí ìkànnì wa kọ́ ni ìsọfúnni náà máa pa mọ́ sí, orí browser tí ẹni náà fi ń lọ sórí ìkànnì ni. Torí náà, irú àwọn ìsọfúnni yìí kì í lọ́jọ́ tó máa pa rẹ́, torí ó máa wà lórí browser yẹn títí, àfi tí ẹni náà bá pa àwọn ìsọfúnni tó wà lórí browser ẹ̀ rẹ́.