Yorùbá
Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí JWEVENT.ORG Ń Lò
/assets/ct/79e1b14fff/images/syn_placeholder_sqr.png

Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí JWEVENT.ORG Ń Lò

Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí JWEVENT.ORG Ń Lò

Oríṣiríṣi ìsọfúnni kéékèèké ló wà, iṣẹ́ wọn sì yàtọ̀ síra, àmọ́ gbogbo wọn ló máa jẹ́ kó o lè gbádùn ìkànnì yìí. Àpẹẹrẹ bá a ṣe ń lo àwọn ìsọfúnni kéékèèké àtàwọn ohun míì tó jọ ọ́ ló wà nísàlẹ̀ yìí.

Orúkọ

Ìdì

Ìgbà

Oríṣi

delidno

Ó máa ń jẹ́ ká lè darí ẹnì kan pa dà sí ọ̀nà tó kọ́kọ́ gbà wọlé sórí ìkànnì náà.

Ọdún kan

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

cnvlang

Ó máa ń jẹ́ kí ẹnì kan lè wọ ìkànnì náà tààràtà ní èdè tó ti yàn tẹ́lẹ̀ lórí https://jwevent.org/.

Ọdún kan

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

Tún wo Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí Àwọn Ìkànnì Wa Ń Lò.