IṢẸ́ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ Yíyàn Láti Sin Jèhófà 1 SÁMÚẸ́LÌ ORÍ 1-3 Ìtọ́ni fún Àwọn Òbí: Kí ìdílé rẹ fi àwọn nǹkan yìí kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pa pọ̀. Wà á jáde Yíyàn Láti Sin Jèhófà IṢẸ́ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ Yíyàn Láti Sin Jèhófà 1 SÁMÚẸ́LÌ ORÍ 1-3 Ìtọ́ni fún Àwọn Òbí: Kí ìdílé rẹ fi àwọn nǹkan yìí kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pa pọ̀. Wà á jáde Yíyàn Láti Sin Jèhófà Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Iṣẹ́ Ìjọsìn Ìdílé O Tún Lè Wo KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Eré Bíbélì Nípa Sámúẹ́lì Sámúẹ́lì bẹ̀rẹ̀ sí í sin Ọlọ́run nígbà tó wà lọ́mọdé. Báwo lo ṣe lè ṣe bí tiẹ̀? KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Bíbélì Nípa Hánà Ọlọ́run dáhùn àdúrà pàtó tí Hánà gbà. ERÉ ALÁWÒRÁN Sámúẹ́lì ní Tẹ́ńpìlì Báwo ni Jèhófà ṣe bù kún Sámúẹ́lì? Tẹ eré yìí jáde, so àwọn àmì tó-tò-tó inú rẹ̀ pọ̀, kó o sì ka ìtàn náà nínú Bíbélì. ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ Sámúẹ́lì Yàn Láti Sin Jèhófà Sámúẹ́lì rí àwọn ohun burúkú tí àwọn tó wà nípò àṣẹ ń ṣe nínú àgọ́ ìjọsìn. Kí ló ràn Sámúẹ́lì lọ́wọ́ láti máa sin Jèhófà nígbà tí àwọn míì yàn láti máa ṣe ohun tó burú? KỌ́ ỌMỌ RẸ Sámúẹ́lì Ń Bá A Lọ Láti Máa Ṣe Ohun tí Ó Dára Báwo lo ṣe lè fìwà jọ Sámúẹ́lì, kó o máa ṣe ohun tó tọ́, tí àwọn èèyàn bá tiẹ̀ ń ṣe ohun tí ò dáa? Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.