IṢẸ́ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ Ọ̀rẹ́ Adúróṣinṣin RÚÙTÙ ORÍ 1-4 Ìtọ́ni fún Àwọn Òbí: Kí ìdílé rẹ fi àwọn nǹkan yìí kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pa pọ̀. Wà Á Jáde Ọ̀rẹ́ Adúróṣinṣin IṢẸ́ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ Ọ̀rẹ́ Adúróṣinṣin RÚÙTÙ ORÍ 1-4 Ìtọ́ni fún Àwọn Òbí: Kí ìdílé rẹ fi àwọn nǹkan yìí kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pa pọ̀. Wà Á Jáde Ọ̀rẹ́ Adúróṣinṣin Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Iṣẹ́ Ìjọsìn Ìdílé O Tún Lè Wo KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Eré Bíbélì Nípa Rúùtù Kí nìdí tí Rúùtù fi múra tán láti kúrò ní ìlú ìbílẹ̀ rẹ̀? Tẹ káàdì eré Bíbélì yìí kó o lè rí ìdáhùn sí ìbéèrè yìí. KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Bíbélì Náómì Náómì ní kí àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ máa pe òun ní orúkọ míì. ERÉ ALÁWÒRÁN Ọ̀rẹ́ Náómì Tó Jẹ́ Adúróṣinṣin Eré aláwòrán yìí á jẹ́ kí àwọn ọmọ ọdún 3 ati 6 kọ́ nípa Rúùtù àti Náómì. ERÉ ALÁWÒRÁN Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àwọn Ànímọ́ Rúùtù Eré aláwòrán yìí á jẹ́ kí àwọn ọmọ ọdún 6 sí 8 lè kọ́ bí wọ́n ṣe máa jẹ́ ọ̀rẹ́ rere. ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ Ọ̀rẹ́ Adúróṣinṣin Ni Rúùtù Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Rúùtù kì í ṣe ọmọ Ísírẹ́lì, ìdúróṣinṣin rẹ̀ mú kó lè jèrè ojú rere Ọlọ́run kó sí rí ìbùkún tó pọ̀ gbà. Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.