ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ Àwọn Ànímọ́ Tó Yẹ Kí Ọ̀rẹ́ Rere Ní TẸ̀ Ẹ̣́ Ṣe àpótí àwòrán kan tó máa ní àwọn ànímọ́ tí wàá fẹ́ kí ọ̀rẹ́ rere ní. Wà á jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Eré Ìkẹ́kọ̀ọ́ O Tún Lè Wo ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ Ọ̀rẹ́ Adúróṣinṣin Ni Rúùtù Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Rúùtù kì í ṣe ọmọ Ísírẹ́lì, ìdúróṣinṣin rẹ̀ mú kó lè jèrè ojú rere Ọlọ́run kó sí rí ìbùkún tó pọ̀ gbà. ERÉ ALÁWÒRÁN Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àwọn Ànímọ́ Rúùtù Eré aláwòrán yìí á jẹ́ kí àwọn ọmọ ọdún 6 sí 8 lè kọ́ bí wọ́n ṣe máa jẹ́ ọ̀rẹ́ rere. ERÉ ALÁWÒRÁN Ọ̀rẹ́ Náómì Tó Jẹ́ Adúróṣinṣin Eré aláwòrán yìí á jẹ́ kí àwọn ọmọ ọdún 3 ati 6 kọ́ nípa Rúùtù àti Náómì. KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Eré Bíbélì Nípa Rúùtù Kí nìdí tí Rúùtù fi múra tán láti kúrò ní ìlú ìbílẹ̀ rẹ̀? Tẹ káàdì eré Bíbélì yìí kó o lè rí ìdáhùn sí ìbéèrè yìí. IṢẸ́ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ Ọ̀rẹ́ Adúróṣinṣin Ìtọ́ni tó wà fún àwọn òbí yìí máa jẹ́ kí ẹ̀yin òbí lè fi ìtàn Bíbélì nípa Rúùtù kọ́ àwọn ọmọ yín ní àwọn ànímọ́ tó yẹ kí ọ̀rẹ́ rere ní. Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.