Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ERÉ ALÁWÒRÁN

Wọ́n Rí Mósè, Ọmọ Jòjòló

Wa àwòrán tó o lè kùn yìí jáde, kó o sì dárúkọ àwọn mẹ́ta tó wà ní Odò Náílì.