ERÉ ALÁWÒRÁN Sólómọ́nì Hùwà Ọlọgbọ́n TẸ̀ Ẹ̣́ Wa eré aláwòrán yìí jáde kí o sì tẹ̀ ẹ́, kẹ́ ẹ fi kẹ́kọ̀ọ́ nípa Sólómọ́nì Ọba. Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Eré Aláwòrán O Tún Lè Wo KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Eré Bíbélì Nípa Sólómọ́nì Wa káàdì eré Bíbélì yìí jáde, kó o sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa Sólómọ́nì Ọba. ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ Jèhófà Fún Sólómọ́nì ní Ọgbọ́n Kò sí ọba tó ní ọgbọ́n tó Sólómọ́nì láyé yìí. Báwo ló ṣe di ọlọ́gbọ́n? Àwọn àṣìṣe wo ló sì ṣe nígbà tó yá? Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.