Yorùbá
Kí La Rí Kọ́ Lára Kéènì àti Ébẹ́lì?
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502012384/univ/art/502012384_univ_sqr_xl.jpg

ERÉ ALÁWÒRÁN

Kí La Rí Kọ́ Lára Kéènì àti Ébẹ́lì?

Wa eré aláwòrán yìí jáde kí o sì tẹ̀ ẹ́, ya àwòrán náà tán, kí ìwọ àti ìdílé rẹ jọ dáhùn àwọn ìbéèrè tó wà níbẹ̀.