ERÉ ALÁWÒRÁN Áńgẹ́lì Kan Mú Kí Gídíónì Lókun TẸ̀ Ẹ̣́ Kun àwòrán áńgẹ́lì tó mú kí Gídíónì lókun. Wà á jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Eré Aláwòrán O Tún Lè Wo KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Bíbélì Nípa Gídíónì Ẹ̀rù kọ́kọ́ ń bà á, àmọ́ ó wá di onígboyà. ERÉ ALÁWÒRÁN Jèhófà Máa Ń Dáhùn Àdúrà Tó Ṣe Pàtó Àwọn ọmọ ọdún mẹ́fà sí mẹ́jọ máa gbádùn eré yìí, torí ó kọ́ wọn pé ó dáa kí wọ́n máa gbàdúrà tó ṣe pàtó. IṢẸ́ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ Bí Jèhófà Ṣe Ń Mú Ká Lókun Ẹ lo àwọn eré yìí pẹ̀lú Àwòrán Ìtàn Bíbélì nípa Gídíónì nígbà ìjọsìn ìdílé yín. ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ Jèhófà Fún Gídíónì Lókun Àwọn ọmọ ogun Gídíónì ṣẹ́gun àwọn ọmọ ogun Mídíánì, bó tiẹ̀ jẹ́ pé 450 ọmọ ogun Mídíánì ni ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn dojú kọ. ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ FÚN ÀWỌN ỌMỌDÉ Àwọn Arákùnrin àti Arábìnrin Wa Ń Mú Ká Lókun Jẹ́ kí àwọn ọmọ rẹ mọ bí wọ́n ṣe lè ran àwọn ọ̀rẹ́ wọn lọ́wọ́ àti bí àwọn ọ̀rẹ́ wọn ṣe lè ran àwọn náà lọ́wọ́. Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.