Yorùbá
Àsìkò Eré Tàbí Àsìkò Dídákẹ́
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502016121/univ/art/502016121_univ_sqr_xl.jpg

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Àsìkò Eré Tàbí Àsìkò Dídákẹ́

Ẹ̀kọ́ Bíbélì yìí á jẹ́ kí àwọn ọmọdé kọ́ bó ṣe yẹ kí wọ́n máa ṣe tí wọ́n bá wà níbi tá a ti ń jọ́sìn Ọlọ́run.