Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ẹ̀kọ́ 13: Jèhófà Á Jẹ́ Kó O Nígboyà

Ẹ̀kọ́ 13: Jèhófà Á Jẹ́ Kó O Nígboyà

Ṣé ẹ̀rù ti bà ẹ́ rí láti sọ̀rọ̀ nípa Jèhófà? Báwo ni Jèhófà ṣe lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè nígboyà?

Tún Wo

ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Báwo Ni Jèhófà Ṣe Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Kó O Lè Nígboyà?

Jèhófà á ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè nígboyà bí ọ̀dọ́bìnrin ọmọ Ísírẹ́lì yẹn.