Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ẹ̀kọ́ 25: Bó O Ṣe Lè Ní Ọ̀rẹ́

Ẹ̀kọ́ 25: Bó O Ṣe Lè Ní Ọ̀rẹ́

Ọ̀rẹ́ gidi lè jẹ́ ọmọdé tàbí àgbàlagbà, tí wọ́n bá ṣáà ti nífẹ̀ẹ́ Jèhófà. Àwọn wo ni ọ̀rẹ́ ẹ?

Tún Wo

ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Máa Bá Àwọn Èèyàn Gidi Ṣọ̀rẹ́!

Kí nìdí tó fi dáa kó o ní àwọn ọ̀rẹ́ kan tó jẹ́ àgbàlagbà?