Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ

Ọlọ́run Rán Mósè Lọ sí Ilẹ̀ Íjíbítì

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bí Jèhófà Ọlọ́run ṣe fi hàn pé òun lágbára ju Fáráò ọba Íjíbítì tó jẹ́ olóríkunkun lọ. Ka ọ̀rọ̀ inú àwòrán ìtàn Bíbélì yìí lórí ìkànnì wa tàbí kó o tẹ̀ ẹ́ jáde.