Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI GAN-AN? (ÌWÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Ojú Tí Ọlọ́run Fi Ń Wo Ẹ̀mí Ni Kí Ìwọ Náà Máa Fi Wò Ó (Apá 1)

Orí kẹtàlá ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Kí nìdí tó fi yẹ ká jẹ́ kí ẹ̀mí jọ wá lójú? Báwo la ṣe lè fi hàn pé ẹ̀mí ara wa àti ti àwọn ẹlòmíì jọ wá lójú?