Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI GAN-AN? (ÌWÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Gbé Ìgbé Ayé Tó Múnú Ọlọ́run Dùn (Apá 2)

Orí kejìlá ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Wo ohun tí Bíbélì fi kóni nípa bí àwọn tó jẹ́ ọ̀rẹ́ Ọlọ́run ṣe lè jẹ́ olóòótọ́ sí i láìka àtakò èyíkéyìí sí.