Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI?

Ìràpadà—Ẹ̀bùn Tó Ṣeyebíye Jù Lọ Tí Ọlọ́run Fúnni (Apá 2)

Orí karùn-ún ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Wo bí ìràpadà náà ṣe lè ṣe wá láǹfààní àti ohun tá a lè ṣe ká lè fi hàn pé a mọrírì rẹ̀.