Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI GAN-AN? (ÌWÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Ohun Tó O Lè Ṣe Kí Ìdílé Rẹ Lè Jẹ́ Aláyọ̀ (Apá 1)

Orí kẹrìnlá ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Kí ló lè mú kí ìgbéyàwó láyọ̀? Àǹfààní wo ni ìmọ̀ràn Bíbélì lè ṣe àwọn tọkọtaya?