Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

IBI TÍ MO KỌ ÈRÒ MI SÍ

Bó O Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tó O Gbà Gbọ́ Nípa Kéèyàn Máa Fẹ́ Ọkùnrin Tàbí Obìnrin Bíi Tiẹ̀

Ìwé yìí máa jẹ́ kó o lè ṣàlàyé ọ̀rọ̀ yìí fún ẹnì kan lọ́nà tó máa mú kó ronú jinlẹ̀, bó tiẹ̀ jẹ́ pé ẹnu àwọn èèyàn ò kò lórí ọ̀rọ̀ yìí.