IBI TÍ MO KỌ ÈRÒ MI SÍ Pinnu Ẹni Tí Wàá Fi Ṣe Àwòkọ́ṣe TẸ̀ Ẹ̣́ Ìwé yìí máa jẹ́ kó o mọ ẹni tí wàá fi ṣe àwòkọ́ṣe. Wà á jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ ìwé àjákọ Ọ̀dọ́ O Tún Lè Wo ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Báwo Ni Mo Ṣe Lè Rẹ́ni Tó Dáa Fi Ṣe Àwòkọ́ṣe? Tó o bá rí ẹni tó dáa tó o lè tẹ̀lé àpẹẹrẹ rẹ̀, ìyẹn máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti yẹra fún ìṣòro, ọwọ́ rẹ máa tẹ àwọn àfojúsùn rẹ, wà á sì ṣe àṣeyọrí. Àmọ́ àpẹẹrẹ tani kó o tẹ̀lé? ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Ṣó Yẹ Kí N Mú Àwọn Míì Lọ́rẹ̀ẹ́ Yàtọ̀ Sáwọn Tá A Ti Jọ Ń Ṣọ̀rẹ́? Tó o bá wà láàárín àwọn pàtó kan tẹ́ ẹ ti jọ ń ṣọ̀rẹ́, ó lè mára tù ẹ́, àmọ́ kì í fìgbà gbogbo ṣàǹfààní. Kí nìdí? ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Kí O Máa Ṣe Bí Àwọn Tí Ò Ń Wò Nínú Fíìmù Tàbí Lórí Tẹlifíṣọ̀n?—Apá 1: Fún Àwọn Ọ̀dọ́bìnrin Ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ tó ń ṣe bí àwọn èèyàn tó wà nínú fíìmù tàbí lórí tẹlifíṣọ̀n rò pé àwọn ń ṣe ohun tó dáa, wọn ò mọ̀ pé ìwà oníwà làwọn ń kọ́. ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Kí O Máa Ṣe Bí Àwọn Tí Ò Ń Wò Nínú Fíìmù Tàbí Lórí Tẹlifíṣọ̀n?—Apá 2: Fún Àwọn Ọkùnrin Sé àwọn èèyàn á gba tìẹ tó o bá ń ṣe bíi ti àwọn tí ò ń rí nínú fíìmù tàbí nínú ìpolówó? OHUN TÁWỌN OJÚGBÀ RẸ SỌ Cameron Gbé Ìgbésí Ayé Tó Dára Jù Lọ Ṣé o fẹ́ káyé ẹ nítumọ̀? Gbọ́ bí Cameron ṣe ń sọ bí ayọ̀ rẹ̀ ṣe pọ̀ tó ní ibi tí kò lérò.