IBI TÍ MO KỌ ÈRÒ MI SÍ Bí Mo Ṣe Lè Mú Àwọn Míì Lọ́rẹ̀ẹ́ TẸ̀ Ẹ̣́ Ìwé yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè bá onírúurú èèyàn ṣọ̀rẹ́. Wà á jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ ìwé àjákọ Ọ̀dọ́ O Tún Lè Wo ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Ṣó Yẹ Kí N Mú Àwọn Míì Lọ́rẹ̀ẹ́ Yàtọ̀ Sáwọn Tá A Ti Jọ Ń Ṣọ̀rẹ́? Tó o bá wà láàárín àwọn pàtó kan tẹ́ ẹ ti jọ ń ṣọ̀rẹ́, ó lè mára tù ẹ́, àmọ́ kì í fìgbà gbogbo ṣàǹfààní. Kí nìdí? ÀWỌN ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ Ta Ni Ọ̀rẹ́ Tòótọ́? Kò ṣòro rárá láti ní ọ̀rẹ́ burúkú, àmọ́ báwo ni o ṣe lè rí ọ̀rẹ́ tòótọ́ OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ọ̀rẹ́? Àwọn ọ̀rẹ́ gidi máa ń jẹ́ ká níwà tó dáa. Fọgbọ́n yan àwọn ọ̀rẹ́ rẹ! JÍ! Báwo Lèèyàn Ṣe Lè Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Gidi? JÍ! Àwọn Wo Ni Ọ̀rẹ́ Mi Tòótọ́?