ÀWỌN ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ Ohun Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Eré Ìdárayá TẸ̀ Ẹ̣́ Ohun Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Eré Ìdárayá Ṣé ó yẹ kí eré ìdárayá wà lára àwọn nǹkan tó ṣe pàtàkì jù láyé rẹ? Máà bínú, ètò tó o fi ń wo fídíò kò ṣiṣẹ́. Wa Fídíò Yìí Jáde O Tún Lè Wo ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Eré Ìdárayá? Ṣàyẹ̀wò irú eré tó ò ń ṣe, bó o ṣe ń ṣe é àti bí àkókò tó o fi ń ṣe eré ọ̀hún bá ṣe pọ̀ tó. JÍ! Kí Làwọn Èèyàn Ń Rí Nínú Eré Tó Léwu? Inú àwọn ọ̀dọ́ máa ń dùn gan-an tí wọ́n bá ń ṣe irú àwọn eré báyìí, wọ́n máa ń fẹ́ fi hàn pé koko lara àwọn le bó tiẹ̀ jẹ́ pé ohun tí wọ́n ń ṣe lè pa wọ́n lára. Ṣé ó máa ń wu ìwọ náà láti ṣe irú àwọn eré bẹ́ẹ̀? ILÉ ÌṢỌ́ Mo Fẹ́ràn Baseball Gan-an! Eré ìdíje ló gba Samuel Hamilton lọ́kàn jù, àmọ́ ẹ̀kọ́ Bíbélì yí ìgbésí ayé rẹ̀ pa dà. JÍ! Eré Ìdárayá Àwọn Èwe—Ìwà Ipá Tuntun Tó Ń tàn Kálẹ̀