ÀWỌN ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Lóòótọ́? TẸ̀ Ẹ̣́ Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Lóòótọ́? Kí ló lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí àwọn ìṣòro tó o ní bó o ṣe ń dàgbà? Máà bínú, ètò tó o fi ń wo fídíò kò ṣiṣẹ́. Wa Fídíò Yìí Jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Àwọn Eré Ojú Pátákó Ọ̀dọ́ O Tún Lè Wo OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ Kí Ni Bíbélì? Bẹ̀rẹ̀ ìrìn-àjò tó lárinrin lọ sínú Bíbélì tí í ṣe ọ̀rọ̀ Ọlọ́run. ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ràn Mí Lọ́wọ́?—Apá Kìíní: Wo Ohun Tó Wà Nínú Bíbélì Tó bá ṣẹlẹ̀ pé o rí àpótí ìṣura ńlá kan, ó dájú pé ó máa wù ẹ́ láti mọ nǹkan tó wà nínú ẹ̀? Bíbélì ò yàtọ̀ sí àpótí ìṣura. Àwọn ìṣura ọgbọ́n tó pọ̀ gan-an tó sì wúlò ló wà nínú ẹ̀. ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ PÀTÀKÌ INÚ BÍBÉLÌ Ibo La Ti Lè Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì Nípa Ìgbésí Ayé? Ṣé àwọn ìbéèrè kan wà tó ò ń wá ìdáhùn sí, bí ọ̀rọ̀ nípa ìgbésí ayé, ikú àtohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú? Ibì kan wà tó o ti lè rí ìdáhùn. ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ PÀTÀKÌ INÚ BÍBÉLÌ Ṣe Òótọ́ Ni Ọ̀rọ̀ Inú Bíbélì? Tó bá jẹ́ pé Ọlọ́run ló ni Bíbélì, á jẹ́ pé kò sí ìwé míì tá a lè fi í wé. OHUN TÁWỌN OJÚGBÀ RẸ SỌ Àwọn Ọ̀dọ́ Sọ̀rọ̀ Nípa Kíka Bíbélì Ìwé kíkà kì í fìgbà gbogbo rọrùn, àmọ́ téèyàn bá ń ka Bíbélì, ó lérè. Àwọn ọ̀dọ́ mẹ́rin ṣàlàyé àǹfààní tí wọ́n ń rí bí wọ́n ṣe ń ka Bíbélì.