ATỌ́NÀ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? (Apá 2)

Yorùbá
Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? (Apá 2)
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502015249/univ/art/502015249_univ_sqr_xl.jpg

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI?

Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? (Apá 2)

Orí kẹjọ ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Kí ni àwọn nǹkan tí Ìjọba Ọlọ́run ti gbé ṣe? Kí làwọn nǹkan tó máa ṣe lọ́jọ́ iwájú? Kọ́ nípa ohun tí Bíbélì sọ.