Yorùbá
Ìrìbọmi Ló Máa Fìdí Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Ọlọ́run Múlẹ̀ (Apá 1)
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502017159/univ/art/502017159_univ_sqr_xl.jpg

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI GAN-AN? (ATỌ́NÀ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Ìrìbọmi Ló Máa Fìdí Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Ọlọ́run Múlẹ̀ (Apá 1)

Orí kejìdínlógún ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì káwọn Kristẹni ṣèrìbọmi? Kí ló yẹ kó sún àwọn Kristẹni ṣèrìbọmi? Wo ohun tí Bíbélì sọ.