Yorùbá
Bí Àwọn Ẹyẹ Ṣe Ń Kọrin​—Ta Ló Ṣiṣẹ́ Àrà Yìí?
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502200145/univ/art/502200145_univ_sqr_xl.jpg
ijwwd àpilẹ̀kọ 42

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Bí Àwọn Ẹyẹ Ṣe Ń Kọrin

Bí Àwọn Ẹyẹ Ṣe Ń Kọrin

Ẹ̀yà ara kán wà tó máa ń gbé ohùn jáde lára àwọn ẹyẹ, ara wọn nìkan lati lè rí i, ẹ̀yà yìí ló máa ń jẹ́ kí wọ́n lè kọ oríṣiríṣi orin títí kan àwọn tó díjú gan-an.