Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Imú Erin

Imú Erin

Iṣẹ́ ọ̀nà tó ń yani lẹ́nu ni imú erin jẹ́, kódà onírúurú àrà ni erin lè fi imú ẹ̀ dá.