Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Bí Afẹ́fẹ́ Oxygen Ṣe Ń Lọ Káàkiri Ara

Bí Afẹ́fẹ́ Oxygen Ṣe Ń Lọ Káàkiri Ara

Báwo ni sẹ́ẹ̀lì pupa inú ẹ̀jẹ̀ ṣe ń gbé afẹ́fẹ́ oxygen látinú ẹ̀dọ̀fóró lọ sí gbogbo ibi tí ara ti nílò ẹ̀, lásìkò tó nílò ẹ̀ gẹ́lẹ́?