Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Àwọn Ohun Alààyè Ń Ṣọ́ Agbára Wọn Lò

Àwọn Ohun Alààyè Ń Ṣọ́ Agbára Wọn Lò

Ọ̀nà tó ṣàrà ọ̀tọ̀ làwọn ohun alààyè gbà ń rí agbára, ó sì jọni lójú gan-an bí wọ́n ṣe ń fọgbọ́n lo agbára náà.