Tọkọtaya Aláyọ̀: Tí Èrò Yín Bá Yàtọ̀ Síra TẸ̀ Ẹ̣́ Tọkọtaya Aláyọ̀: Tí Èrò Yín Bá Yàtọ̀ Síra Ẹ máa fọwọ́ sowọ́ pọ̀ tí èrò yín bá tiẹ̀ yàtọ̀ síra. Máà bínú, ètò tó o fi ń wo fídíò kò ṣiṣẹ́. Wa Fídíò Yìí Jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Ìgbéyàwó Ìgbéyàwó àti Ìdílé O Tún Lè Wo ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ Tí Èrò Yín Ò Bá Jọra Tí tọkọtaya ò bá gbọ́ra wọn yé, báwo ni wọ́n ṣe lè yanjú ẹ̀, kí wọ́n sì wà lálàáfíà pẹ̀lú ara wọn? ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ PÀTÀKÌ INÚ BÍBÉLÌ Báwo Ni Ọlọ́run Ṣe Fẹ́ Kí Ìgbéyàwó Rí? Ọlọ́run fẹ́ kí ìgbéyàwó rẹ̀ dùn bí oyin. Àwọn ìmọ̀ràn tó wà nínú Bíbélì ti ran ọ̀pọ̀ tọkọtaya lọ́wọ́. JÍ! Bo O Se Le Ni Ajose To Daa Pelu Awon Ana Re Ohun meta ti ko ni je ki isoro to o ni pelu awon ana re da wahala sile laarin iwo ati oko tabi iyawo re. ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Ẹnì Kejì Ẹ Bá Hùwà Tó Ń Múnú Bí Ẹ Dípò tí wàá fi jẹ́ kí ìwà tó ń múnú bí ẹ dá ìjà sílẹ̀, kọ́ bó o ṣe lè máa fi ojú tó yàtọ̀ wo nǹkan. ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ Tọkọtaya Aláyọ̀: Ẹ Máa Bọ̀wọ̀ Fúnra Yín Bíbélì máa jẹ́ kẹ́ ẹ túbọ̀ máa bọ̀wọ̀ fún ara yín tó bá jẹ́ pé ẹ kì í ṣe bẹ́ẹ̀ tẹ́lẹ̀.