Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ | ÌGBÉYÀWÓ

Ẹ Máa Fìfẹ́ Hàn Sí Ara Yín

Ẹ Máa Fìfẹ́ Hàn Sí Ara Yín

Tí tọkọtaya bá nífẹ̀ẹ́ ara wọn tí wọ́n sì ń ṣìkẹ́ ara wọn, ilé wọn máa tòrò.