Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

September 4-​10

ÌSÍKÍẸ́LÌ 42-45

September 4-​10
 • Orin 26 àti Àdúrà

 • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

 • Ìjọsìn Mímọ́ Pa Dà Bọ̀ Sípò!”: (10 min.)

  • Isk 43:​10-12​—Jèhófà fi ìran tẹ́ńpìlì han Ìsíkíẹ́lì, kó bàa lè mú kí àwọn Júù tó wà nígbèkùn ronú pìwà dà, kó sì fi wọ́n lọ́kàn balẹ̀ pé ìjọsìn mímọ́ máa pa dà bọ̀ sípò (w99 3/1 8 ¶3; it-2 1082 ¶2)

  • Isk 44:23​—Àwọn àlùfáà máa fún àwọn èèyàn náà ní ìtọ́ni nípa “ìyàtọ̀ láàárín ohun tí kò mọ́ àti ohun tí ó mọ́”

  • Isk 45:16​—Àwọn èèyàn náà máa fọwọ́ sowọ́ pọ̀ pẹ̀lú àwọn tí Jèhófà yàn láti mú ipò iwájú (w99 3/1 10 ¶10)

 • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

  • Isk 43:8, 9​—Báwo ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe sọ orúkọ Ọlọ́run di ẹlẹ́gbin? (it-2 467 ¶4)

  • Isk 45:9, 10—Kí ni Jèhófà ń fẹ́ kí àwọn tó bá fẹ́ rí ojú rere rẹ̀ máa ṣe? (it-2 140)

  • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

  • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

 • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 44:1-9

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

 • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI