Àdúrà wà lára nǹkan tẹ̀mí tí Dáníẹ́lì máa ń ṣe déédéé. Kò gbà kí àṣẹ ọba tàbí ohunkóhun míì dí ìjọsìn òun lọ́wọ́

6:10

Kí ni àwọn nǹkan tẹ̀mí tó yẹ ká máa ṣe déédéé?